The first 200 lines.
- -
WAKATI MEJILA SEYIN
- -Báwo ni?
Mo wa pa.
- Báwo ni ieẹ̀ lóni? -Adúpẹ́. Iwo nko?
- Se o wa? -Ba wo ni?
Wo, isẹ́ yì ti sú mi jàre, má jẹ̀ ki ntàn ẹ́.
-Ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ gan yi ti sú mi. -
-O ma ma farada wọn na ni. pẹ̀lẹ́. -Wo…
Pele. Kilo wa lori e?
Boya eruku ni abi efun ikowe.
Se mo ma ri e to ba ya?
Mo fẹ́ lọ r'Olùsọ́
-Oti. -
Ọwọ́ kan péré lo ma sé, o ní pẹ́.
Iwo!
Eele?
Báwo ni? So ti setán ni school?
-Maami, e wo ohun ti mo ti se. - O ma rewa!
Sweetie, jọ mo fẹ́ ko bámi sáré
gbowó ni bank ni.
Oti o. Isẹ́ pọ̀ lọ́wọ́ mi gan o.
Kí la ma wá se bayi?
Torí to ba lọ bámi gbowó,
kòsí nkan t'íwọ àti ọmọ ẹ ma jẹ́ lálẹ́ yi.
-O da, mo ti gbọ́. -Kaasan! Bawo ni?
Customers pọ nbí bàyí gan ni.
Jọ̀ọ́ ntorí Ọlọ́run ọkọ mí. Mmm?
-Mà á lọ sẹ́, mo ti gbọ́ -Kaasan! Bawo ni?
O ní pẹ́, ọwọ́ kán péré lo ma se.
Wo, jẹ́ ki ntètè ma lọ rí Olùsọ́ jàre.
Ẹh ẹh? Oda, to bá ti rí Olùsọ́
- jẹ́ ki nmọ bó ṣe lọ. - O da.
Eh kí lo nṣe nbẹyẹn, to parí lataarọ?
Ha, oga mi.
Kiní yi kan stubborn anyhow ni, mo ti fẹ́ pa rí ẹ̀.
Ìyẹn lò nbája lat'ẹkan?
Eh eh, ẹyín! Lateef nkọ́?
Haa oga, a mọ bi tó gbà lọ.
Ẹ sa mọ npe ìdí ẹ o kin dúró soju kan.
-Se o mo pe graduate ni won, -
mechanical engineer.
Óyá, wo bi, kuò nbẹyẹn, kuro nbẹyẹn.
-Mo ti fe ẹ setán, ọ̀ga mi. -Kuo nbẹyen sẹ.
- Mo le sé e, diẹ lo ma ku. -Jẹ́kí Lateef dé kó wa parí ẹ, haa.
O fẹ́ ba motto oní motto jẹ fun mi ni?
Ta nìyẹn?
Ó lè jẹ́ landlord ni. Ma dahun jàre.
-Tani?! Kí ló dé gaan?! -Lateef sílẹ̀kùn yí!
- -Tani?
Tani?
Múmmy mí ló ma jẹ́.
-Múmmy ẹ? -Ẹ, múmmy mi.
Ahn-ahn. Se bi o sọ pe mummy ẹ ti ku ni?!
- Lateef sílẹ́kun yí now! -Fara balẹ! Ha ha!
Sè gbogbo iya to ba bi eniyan gangan ni iya ni?
Ìyá ni mo fi se.
Iyen ni mo so.
Dìde, dìde jọọ! Má kó bá mi! Óyá, oyá.
- -Mò, mò nwá kokoro yẹn ni, mò nwa kokoro.
Sílẹ̀kun yí, my friend!
Gbà, gbà!
-Ah! -Shh!
-Shh!
- -
Ha. Mò tiẹ̀ mọ ibi tí mo sọ kokoro si.
Kokoro yẹn ni mò nwá o.
-Kokoro ni mò nwá. -
Ah ah! Iyabo. Mo rò pé… mo rò pé o fẹ́ travel?
-Òwun da? -Tani? Kini yẹn?
Kòsí èyàn kankan nbí bàyíí Iyabo.
Kòsí èyàn kankan nbí bàyí.
Kòsí eyan kankan nbí.
Kòsí eyan kankan nbí.
Em. ilẹ̀kùn toilet yẹn tii… o tí bàjẹ́.
Lateef, sílẹ̀kùn yí.
Ilẹ̀kùn yẹ́n ti bàjẹ́.
- Mo ti pe carpenter paapaa. - Sílẹ̀kùn yí, my friend!
Aní'lẹ̀kùn yẹn ti bàjẹ̀, carpenter sọ pe
o dalẹ́ k'ówun tó ráye.
O da, ma se iyonu. Kosi wahala.
-Ó dìgba ti n´mo bá… -Iyabo jọ ni suru.
- Mo ni iyalenu fun ọ. - Fi mí sílẹ̀! Ye!
- -Kí ló se ẹ́?
Oh! Lateef mo fẹ́ lo toilet, sílẹ̀kùn yí.
Àní eléyi ti bàjẹ́, o lè lo eléyi. O le wọlé
Bóyá ka lọ restaurant kan. Ni tooto, ó ti bàjẹ́.
Àní mo ní mo fẹ lo toilet.
Ọ-Ọlọ́un Ọba ngbọ́, Ọlọ́un, ó ti bàjẹ́.
Ilẹ̀kùn yẹn ti bàjẹ́ pátá pátá.
Aní sílẹ̀kùn yí Lateef.
-Lateef. -Iyabo.
Ma binu. Je kin s'alaiye fun o.
Beeni, mo le s'alaiye fun o.
Alàgbà.
-Ayé mi o lọ síwájú. -Hmm!
-Níbiṣẹ́… kòsí igbega. -Mh!
Nilé gan, ìyàwó mi kàn ṣe bó ṣe wùn ní…
torípé ó lówó jù mí lọ.
Ó ti sú mi, ó ti sú mi.
Ǹjẹ́ o mú 50,000 yẹn dání?
-O wà nbí. -Hmm.
Kò dẹ̀ ní daa fún ẹ.
So, isékuse to má nse nlé ọkọlọ́kọ nì yí?
Mi ò se nkankan.
Eh, kílódé to se wá sápamọ́ sínu toilet?
Mí o sápamọ
Àwọ́n òbí ẹ dẹ̀ ma rò pé ilé ìwé lo wa.
Àsé ìranù lò nsé kaakiri, to ntẹ̀lé
ọkùnrin kaakiri àdúgbò.
Kí ló sẹlẹ̀ gan gan ná?
-Ah! -Eh? Kíni?
-Laide. -Jẹ́ kin sọ̀rọ̀ o.
Ẹ dẹ̀ nsọ̀rọ̀ sí mi látaarọ.
Kí ló sẹlẹ̀? S'ọ́kọ yín ni?
-Sèbí, ó jọ rún àwa méjèjì ni? -Ah!
Lateef. Lateef!
So ri bí asẹ́wó ẹ sé nbá mi sọ̀rọ̀ torí tì ẹ?
-Eh, mi ò kín se aṣewó o. -Hee!
Jọ, fún mi ní bàtà mi. Bá nmú bàtà mi.
Sémi lọmọ yí nbá sọ̀rọ̀ bẹ yẹn?
Oti o, wa nbi. Kilode ti o n sa lo?
Mo si n ba yin soro.
Lateef.
So, gbogbo pálapàla to nse nì yí?
Em, ma bínú ntorí Ọlọ́un
Ọlóun ni mo fi bẹ̀ ẹ́, mo lè explain fun ẹ.
-So ti understand? Má bínú, Iyabo. -Hah!
Kò dẹ̀ ní daa fún ẹ pèlú ẹ̀bẹ̀ tó nbẹ̀ mí.
-Kí lódé to sé nbẹ̀ wọ́n? -Ahn-ahn!
Laide, kíni isoro ẹ?
Kini jẹtijẹ? Kíni problem ẹ? O dẹ̀ dákẹ́!
Mi ò fẹ́ kó dìja. Ha ha!
Tó bá ma dìjà, kó dìjà.
So, gbogbo ìsekúse pálapàla to nse
nínú ilé tí mo fi owó mi sanwó ẹ. Òwun nì yí?
-Ma, ma bínú. -Iyabo.
Ẹ jọ̀ọ́, sé ẹ̀yin lẹ sanwó ẹ, àbí owó ọkọ yín?
Sówó ọkọ yín kọ́ lẹ̀ ná? Ẹ rò páámọ̀?
Kíni itunmọ̀ gbogbo eléyi nsìnyí?
Mi ò like ẹ̀, mi ò fẹ́ kó dìjà o.
Tó bá ma dìjà, kó dìjà, ko yé pariwo lé mi lórí jàre.
Yé pariwo lémi.
-Gbọ́ ná. -Kíni, mi ò lo anywhere.
Kí lelé yi lọ́wọ́ ẹ?
Kò kàn yín. Kílódé?
Laide ò nṣe hand chain mi?
Lateef ló rà á fún mi, kílódé?
Gb'enu e soun!
Ooh so, pẹ̀lú asẹ́wó tó nse, o tún jálè.
Em, bọ, bọ. Mà á rà mii fún ẹ jọ̀ọ.
-Kíni? Mi ò bọ́ nkankan. -Bọ mà á rà mii fún ẹ! Ha!
Bá nmu.
Bọ, mà á rà mii fún ẹ. Ẹ stop ẹ.
-Má se mí lése jọ̀ọ́! -Iyabo, jọ̀ọ́, tori Oloun!
E ma ma yo mi le…
-Ole! Asewo! -Iyabo, e rora.
Mi ò mọ̀ bóyá mo jẹ́'gbẹ́ ẹ́.
Laide, wa maa lo. Maa ba e sọrọ later.
-Iyabo, ma binu. -Ní ko dìde kó bọọta kuro nínú ilé yii.
Laide.
Mo ní ko ní kó dìde, kó bọọta kúrò nnú ilé yii.
Oniranu!
Laide!
Ah!
Laide! Haa!
Kíni?
-Kò mí mọ́ o. -Kíni, kíni kò mí?
-Kò mí mọ́ sẹ́! -So gbádun?
-Ní kó dìde jare! -Laide ti kú! O ti pa yàn!
-Eh! Bàbá gbọ́ ọmọ rẹ. -Àmín!
-Ẹ gb'ogo ẹ̀ fun. Ẹ da padà. -Àmin!
Ẹ gb'ogo fun. Torí a tọrọ,
-A bẹ̀bẹ̀, -Àmin!
-Lórúkọ baba,. -Àmín!
-Àmín! -Àmín!
Ogún ti sẹ́.
-Ìdè ti já. -Halleluyah!
Ogún ti sẹ́, ìdè ti já!
-Ẹ lè dìde. Ìdè ti já. -Ẹ sé Alàgbà
-Ìdè ti já. -Bàbá ti sẹ́gun.
-Bàbá ti sẹ́gun. -Ẹ sé.
Gbọ́ o… kò lè pé ọjọ́ meje tí wa fi gba ìròyìn ayọ̀.
-Ọjọ́ meje. -Ọjọ́ meje, àmọ,
Amo, tí iwó ba ti gbọ́ ìroyìn ayo,
wà á sáré tete, wà á tún padà wá síbí, wà wá san ìdá mẹ́wa.
-Ó se kókó, ó se kókó. -Ó yé mi. Ẹ sé.
-Pele. Ehen! -Ẹ sé, ẹ sée. Se mo le ma lo?
-Shina! -Eh?
M'éléyi wa. M'éléyi wa.
No comments yet. Be the first to leave one.